Oriki Jaguda.

Mo le korin moju ti irin ise o ba lana,
loju omo to ta ide reke

To gbe sun mo mi,

ti emi gaaan o se kuru kere.
Emi ti o mo ni alujo to le je ki omo gbagbe ile.

Mi go iru e ri,
ki olorun ma ba ile ayo me je ni.

Mo le pe ara mi ni oko iyawo, loju aya to mo ere se.

To baa ni igbago,
Ka wo ile mi ka lo dan ra wo, ka ri na.

Ko ma ma wo mi bi pe mi o le.

Eni ga gaaaan,
kilo tun bo lola?

Comments

Popular posts from this blog

The Power of SEX!!!

Lekki Toll Gate Wahala